Àwọn Adájọ́ 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Sisera bá bẹ̀ ẹ́ pé, “Jọ̀wọ́ òùngbẹ ń gbẹ mí, fún mi lómi mu.” Jaeli bá ṣí ìdérí ìgò tí wọ́n fi awọ ṣe, tí wọ́n da wàrà sí, ó fún un ní wàrà mu, ó sì tún da aṣọ bò ó.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:14-24