Àwọn Adájọ́ 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Sisera sá lọ sí àgọ́ Jaeli, aya Heberi, ará Keni, nítorí pé alaafia wà ní ààrin Jabini, ọba Hasori, ati ìdílé Heberi ará Keni.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:10-24