Àwọn Adájọ́ 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Baraki lépa àwọn kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn ọmọ ogun Sisera títí dé Haroṣeti-ha-goimu, wọ́n sì fi idà pa àwọn ọmọ ogun Sisera láìku ẹyọ ẹnìkan.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:11-22