Àwọn Adájọ́ 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí, Heberi ará Keni ti kúrò ní ọ̀dọ̀ àwọn ará Keni yòókù tí wọ́n jẹ́ ìran Hobabu, àna Mose, ó sì pàgọ́ sí ẹ̀bá Kedeṣi lẹ́bàá igi oaku kan ní Saananimu.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:6-13