Àwọn Adájọ́ 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Baraki bá pe àwọn ọmọ Sebuluni ati Nafutali sí Kedeṣi; ẹgbaarun (10,000) ọkunrin ninu wọn ni wọ́n tẹ̀lé Baraki, Debora náà sì bá wọn lọ.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:4-15