Àwọn Adájọ́ 3:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Idà yìí wọlé tèèkùtèèkù, ọ̀rá sì padé mọ́ ọn, nítorí pé kò fa idà náà yọ kúrò ní ikùn ọba, ìfun ọba sì tú jáde.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:15-29