Àwọn Adájọ́ 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ehudu bá fi ọwọ́ òsì fa idà tí ó so mọ́ itan rẹ̀ ọ̀tún yọ, ó sì tì í bọ ọba Egiloni níkùn.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:14-29