Àwọn Adájọ́ 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi ìṣákọ́lẹ̀ náà jíṣẹ́ fún Egiloni, ọba ilẹ̀ Moabu. Egiloni yìí jẹ́ ẹni tí ó sanra rọ̀pọ̀tọ̀.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:9-26