Àwọn Adájọ́ 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ehudu rọ idà olójú meji kan tí kò gùn ju igbọnwọ kan lọ, ó fi bọ inú àkọ̀, ó so ó mọ́ itan rẹ̀ ọ̀tún lábẹ́ aṣọ.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:13-17