Àwọn Adájọ́ 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Egiloni yìí kó àwọn ará Amoni ati àwọn ará Amaleki sòdí, wọ́n lọ ṣẹgun àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n sì gba Jẹriko, ìlú ọlọ́pẹ, lọ́wọ́ wọn.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:4-20