Àwọn Adájọ́ 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, OLUWA sì fún Egiloni, ọba ilẹ̀ Moabu, lágbára lórí wọn, nítorí pé wọ́n ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:6-20