Àwọn Adájọ́ 21:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé nígbà tí àwọn eniyan náà kó ara wọn jọ, ẹnikẹ́ni láti inú àwọn tí ń gbé ìlú Jabeṣi Gileadi kò sí níbẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:3-18