Àwọn Adájọ́ 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bèèrè pé, “Ẹ̀yà wo ninu Israẹli ni kò wá siwaju OLUWA ní Misipa?” Wọ́n rí i pé ẹnikẹ́ni kò wá ninu àwọn ará Jabeṣi Gileadi sí àjọ náà.

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:6-10