Àwọn Adájọ́ 21:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá pinnu pé, “Ọdọọdún ni a máa ń ṣe àjọ̀dún OLUWA ní Ṣilo, tí ó wà ní apá àríwá Bẹtẹli, ní apá ìlà oòrùn òpópó ọ̀nà tí ó lọ láti Bẹtẹli sí Ṣekemu, ní apá gúsù Lebona.”

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:15-23