Àwọn Adájọ́ 21:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn sibẹsibẹ, a kò gbọdọ̀ fi àwọn ọmọ wa fún wọn.” Nítorí pé àwọn ọmọ Israẹli ti búra pé, “Ẹni ègún ni ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ọmọ fún ará Bẹnjamini.”

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:11-25