Àwọn Adájọ́ 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, wọ́n ń bọ oriṣa Baali.

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:10-20