Àwọn Adájọ́ 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìṣọ̀wọ́ àwọn tí wọ́n mọ OLUWA ati ohun tí ó ti ṣe fún Israẹli patapata ni wọ́n kú, àwọn ìran mìíràn sì dìde lẹ́yìn wọn, wọn kò mọ OLUWA, ati gbogbo ohun tí ó ti ṣe fún Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:8-13