Àwọn Adájọ́ 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin mejeeji bá jókòó, wọ́n jẹ, wọ́n mu, lẹ́yìn náà ni baba ọmọbinrin yìí tún dáhùn pé, “Jọ̀wọ́ kúkú dúró ní alẹ́ yìí kí o máa gbádùn ara rẹ.”

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:3-14