Àwọn Adájọ́ 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹrin, wọ́n gbéra ní òwúrọ̀ kutukutu wọ́n fẹ́ máa lọ. Ṣugbọn baba ọmọbinrin náà rọ̀ ọ́ pé kí ó jẹ oúnjẹ díẹ̀ kí ó tó máa lọ, kí ó lè lágbára.

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:4-9