Àwọn Adájọ́ 19:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba arúgbó náà bá dáhùn pé, “Ṣé alaafia ni ẹ dé? Ẹ kálọ, n óo pèsè ohun gbogbo tí ẹ nílò fun yín, ẹ ṣá má sun ìta gbangba níhìn-ín.”

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:12-22