Àwọn Adájọ́ 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá tún ń bá ìrìn àjò wọn lọ, oòrùn ti wọ̀ kí wọ́n tó dé Gibea, ọ̀kan ninu àwọn ìlú ẹ̀yà Bẹnjamini.

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:9-19