Àwọn Adájọ́ 19:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún iranṣẹ rẹ̀ pé, “Jẹ́ kí á lọ sí ọ̀kan ninu àwọn ìlú wọnyi, kí á sì sùn ní Gibea tabi ní Rama.”

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:3-14