Àwọn Adájọ́ 18:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Dani bá ń bá tiwọn lọ, nígbà tí Mika rí i pé wọ́n lágbára ju òun lọ, ó pada sílé rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:24-31