Àwọn Adájọ́ 18:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Dani dá a lóhùn, wọ́n ní, “Má jẹ́ kí àwọn eniyan gbọ́ ohùn rẹ láàrin wa, kí àwọn tí inú ń bí má baà pa ìwọ ati gbogbo ìdílé rẹ.”

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:16-31