Àwọn Adájọ́ 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ní àkókò ìkórè ọkà, Samsoni mú ọmọ ewúrẹ́ kan, ó lọ bẹ iyawo rẹ̀ wò. Nígbà tí ó dé ibẹ̀, ó ní, “Mo fẹ́ wọlé lọ bá iyawo mi ninu yàrá.”Ṣugbọn baba iyawo rẹ̀ kò jẹ́ kí ó wọlé lọ bá a.

Àwọn Adájọ́ 15

Àwọn Adájọ́ 15:1-10