Àwọn Adájọ́ 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá fi iyawo rẹ̀ fún ẹni tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ tímọ́tímọ́ ninu àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ ní àkókò igbeyawo.

Àwọn Adájọ́ 14

Àwọn Adájọ́ 14:10-20