Àwọn Adájọ́ 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò pẹ́ pupọ lẹ́yìn náà, ni ó pada lọ láti lọ mú iyawo rẹ̀. Bí ó ti ń lọ, ó yà wo òkú kinniun tí ó pa, ó bá ọ̀wọ́ oyin ati afárá oyin lára rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 14

Àwọn Adájọ́ 14:1-11