Àwọn Adájọ́ 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó lọ bá ọmọbinrin náà sọ̀rọ̀. Ọmọbinrin náà wù ú gidigidi.

Àwọn Adájọ́ 14

Àwọn Adájọ́ 14:5-17