Àwọn Adájọ́ 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà, ará Sora, láti inú ẹ̀yà Dani, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Manoa; àgàn ni iyawo rẹ̀, kò bímọ.

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:1-9