Àwọn Adájọ́ 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, OLUWA sì fi wọ́n lé àwọn ará Filistia lọ́wọ́. Wọ́n sin àwọn ará Filistia fún ogoji ọdún.

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:1-11