Àwọn Adájọ́ 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dá wọn lóhùn, ó ní, “Bí ẹ bá mú mi pada wálé, láti bá àwọn ará Amoni jagun, bí OLUWA bá sì fi wọ́n lé mi lọ́wọ́ tí mo ṣẹgun wọn, ṣé ẹ gbà pé kí n máa ṣe olórí yín?”

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:8-11