Àwọn Adájọ́ 11:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà Gileadi dá a lóhùn pé, “OLUWA ni ẹlẹ́rìí láàrin àwa pẹlu rẹ pé, ohun tí o bá wí ni a óo ṣe.”

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:2-20