Àwọn Adájọ́ 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jẹfuta dá wọn lóhùn pé, “Ṣebí ẹ̀yin ni ẹ kórìíra mi tóbẹ́ẹ̀ tí ẹ fi lé mi jáde kúrò ní ilé baba mi? Kí ló dé tí ẹ fi wá sọ́dọ̀ mi nígbà tí ìyọnu dé ba yín?”

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:1-9