Àwọn Adájọ́ 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bẹ Jẹfuta, wọ́n ní, “A fẹ́ lọ gbógun ti àwọn ará Amoni, ìwọ ni a sì fẹ́ kí o jẹ́ balogun wa.”

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:5-11