Àwọn Adájọ́ 11:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ̀rẹ̀ sí pa wọ́n láti Aroeri títí dé agbègbè Miniti tí ó fi wọ Abeli Keramimu. Àwọn ìlú tí ó run jẹ́ ogún. Àwọn ọmọ Israẹli sì ṣẹgun àwọn ará Amoni.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:28-39