Àwọn Adájọ́ 11:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹfuta bá rékọjá lọ sọ́dọ̀ àwọn ará Amoni láti bá wọn jagun, OLUWA sì fún un ní ìṣẹ́gun.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:28-39