Àwọn Adájọ́ 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Sihoni kò ní igbẹkẹle ninu àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọn kọjá láàrin ilẹ̀ rẹ̀. Ó bá kó gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ jọ, wọ́n pàgọ́ sí Jahasi, wọ́n sì gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:18-26