Àwọn Adájọ́ 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli bá tún rán oníṣẹ́ sí Sihoni, ọba àwọn ará Amori, tí ó wà ní ìlú Heṣiboni, wọ́n ní, ‘Jọ̀wọ́ jẹ́ kí á gba ilẹ̀ rẹ kọjá lọ sí agbègbè ilẹ̀ tiwa.’

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:13-22