Àwọn Adájọ́ 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Odidi ọdún mejidinlogun ni wọ́n fi ni àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà ní òdìkejì odò Jọdani, ní Gileadi lára. Gileadi yìí wà ní ilẹ̀ àwọn ará Amoni.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:2-9