Àwọn Adájọ́ 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú tún bí OLUWA sí Israẹli ó sì fi wọ́n lé àwọn ará Filistia ati àwọn ará Amoni lọ́wọ́.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:1-12