Àwọn Adájọ́ 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Amoni múra ogun, wọ́n pàgọ́ sí Gileadi, àwọn ọmọ ogun Israẹli náà bá kó ara wọn jọ, wọ́n pàgọ́ tiwọn sí Misipa.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:14-18