Àwọn Adájọ́ 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá kó gbogbo àwọn àjèjì oriṣa tí ó wà lọ́wọ́ wọn dànù, wọ́n sì ń sin OLUWA. Inú bí OLUWA, nítorí ìpọ́njú àwọn ọmọ Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:15-18