Àwọn Adájọ́ 1:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Aṣeri náà kò lé àwọn wọnyi jáde: àwọn ará Ako ati àwọn ará Sidoni, àwọn ará Ahilabu ati àwọn ará Akisibu, àwọn ará Heliba ati àwọn ará Afeki, ati àwọn ará Rehobu.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:24-36