Àwọn Adájọ́ 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Juda ṣẹgun ìlú Gasa ati àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè rẹ̀. Wọ́n ṣẹgun ìlú Aṣikeloni ati Ekironi ati àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè wọn.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:10-22