Àwọn Adájọ́ 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Juda bá àwọn ọmọ Simeoni, arakunrin wọn, lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Kenaani tí wọ́n ń gbé Sefati. Wọ́n gbógun tì wọ́n, wọ́n run wọ́n patapata, wọ́n sì sọ ìlú náà ní Horima.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:13-22