Àwọn Adájọ́ 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n kúrò níbẹ̀, wọ́n lọ gbógun ti ìlú Debiri. (Kiriati Seferi ni orúkọ tí wọ́n ń pe Debiri tẹ́lẹ̀.)

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:5-12