Àwọn Adájọ́ 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Juda tún lọ gbógun ti àwọn ará Kenaani tí wọn ń gbé ìlú Heburoni, (Kiriati Araba ni orúkọ tí wọn ń pe Heburoni tẹ́lẹ̀); wọ́n ṣẹgun Ṣeṣai, Ahimani ati Talimai.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:6-20