Amosi 5:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii, ẹ̀ ń sin ère Sakuti, ọba yín, ati Kaiwani, oriṣa ìràwọ̀ yín, ati àwọn ère tí ẹ ṣe fún ara yín.

Amosi 5

Amosi 5:22-27