Amosi 5:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbọ́, ilé Israẹli, ǹjẹ́ ẹ mú ẹbọ ati ọrẹ wá fún mi ní gbogbo ogoji ọdún tí ẹ fi wà ninu aṣálẹ̀?

Amosi 5

Amosi 5:20-26