Amosi 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli, ọdọmọbinrin, ṣubú,kò ní lè dìde mọ́ lae.Ó di ìkọ̀sílẹ̀ ní ilẹ̀ rẹ̀,kò sì sí ẹni tí yóo gbé e dìde.

Amosi 5

Amosi 5:1-3